Display Videos ( 151 - 175 of: 285 )
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 2/ 3
2015-05-11
Adanwo ti o ba awọn Anọbi Ọlọhun, anfaani ti o wa nibi ki Ọlọhun fi adanwo kan Musulumi ati Okunfa adanwo.
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 1/ 3
2015-05-11
Itumọ adanwo ati orisirisi awọn aworan ti o maa ngba kan ọmọ’niyan.
Pataki Sise Adua Fun Ilu Ẹni
2015-05-06
Idanilẹkọ nipa awọn okunfa gbigba adua, ati wipe ẹniti o ba ni ifẹ si ilu rẹ gbọdọ maa se adua ki ilu naa dara.
Idajọ Kiki Pẹlu Titẹ ati Idọbalẹ Ninu Islam
2015-05-06
Alaye lori wipe kiki eniyan pẹlu titẹ ati idọbalẹ kosi ninu ohun ti ẹsin Islam gba Musulumi laaye lati se.
Ọrọ Nipa Osu Rajab
2015-05-06
Alaye nipa awọn ohun ti o sẹlẹ ninu osu Rajab gẹgẹ bii osu ọwọ ati awọn osu ọwọ yoku.
Ojuse Asiwaju Si Awọn Ọmọlẹyin
2015-05-06
Alaye bi ẹsin Islam se pa asiwaju ni asẹ lati maa se ojuse rẹ lori awọn ọmọlẹyin rẹ, pẹlu apejuwe igbesi aye saabe agba Umar bin Khataab [Ki Ọlọhun Kẹ ẹ]
Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 5/ 5
2015-05-06
Abala yii kun kẹkẹ fun ibeere ati idahun.
Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 4/ 5
2015-05-06
Abala yii kun kẹkẹ fun ibeere ati idahun.
Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 3/ 5
2015-05-06
Bi a se nkirun si oku lara ati awọn ẹkọ ti o rọ mọ ọ
Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 2/ 5
2015-05-06
Awọn isesi ti a kọ fun ẹni ti ọfọ ba sẹ, ati sise alaye diẹ nipa awọn ẹkọ ti o rọ mọ oku wiwẹ.
Ẹkunrẹrẹ Ẹkọ nipa Oku - 1/ 5
2015-05-06
Ipalese silẹ siwaju ki iku too de, ati awọn ojuse wa si ẹni ti npọka iku lọwọ pẹlu awọn ojuse wa si ẹni ti ẹmi sẹsẹ jade lara rẹ
Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 3/ 3
2015-05-06
Itẹsiwaju ninu alaye ọrọ lori awọn ọna ti a le gba ko arisiki jọ.
Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 2/ 3
2015-05-06
Awọn ọna ti a le gba ko arisiki jọ pẹlu awọn ẹri wọn lati inu Alukuraani ati Sunnah.
Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 1/ 3
2015-05-06
Pataki owo ati wipe wiwa owo gbọdọ jẹ lati ọna ti o mọ ti o si jẹ ẹtọ
Alaye Aaya kẹjọ ati ẹkẹsan ninu Suuratul Mumtahinah
2015-04-11
Ohun ti o waye ninu ibanisọrọ yii: (1) Sise daadaa si aladugbo ti kiise Musulumi. (2) Ki ọmọ maa se daadaa si awọn obi rẹ mejeeji ti wọn kiise Musulumi.
Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -3
2015-04-11
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe adadasilẹ sise ni ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) pẹlu awọn ẹri ti wọn fi rinlẹ lori awọn ọrọ wọn.
Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -2
2015-04-11
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe ko si laifi nibi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a).
Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -1
2015-04-11
Ọrọ nipa bi sise ajọdun ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) se bẹrẹ.
Atubọtan-3
2015-04-11
Ni apa yii alaye wa lori okunfa atubọtan daadaa fun eniyan pẹlu awọn apẹẹrẹ ti a o ri lara eniyan, ti njuwe pe iru ẹni bayi ni atubọtan daadaa.
Atubọtan-2
2015-04-11
Ninu apa yii alaye waye lori awọn iwa tabi isesi ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Atubọtan-1
2015-04-11
Alaye itumọ ohun ti a mọ si atubọtan ati awọn isẹ ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-2
2015-03-07
Abala yii jẹ alekun alaye lori awọn ohun ti o maa nmu igbesi aye lọkọ-laya ni itumọ ati idahun si awọn ibeere ti o waye.
Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-1
2015-03-07
Idanilẹkọ yii da lori itumọ lọkọ-laya ati alaye awọn ohun ti o maa njẹ ki igbesi aye lọkọ-laye ni itumọ gẹgẹ bii: Ibẹru Ọlọhun Allah, Sise akiyesi adehun ti ọkunrin maa nse fun obirin nigba ti wọn ko tii gbe ara wọn wọ ile.
Taani Aafa (Alufa)? -3
2015-03-07
Ni abala yii ni awọn idahun ti waye si awọn ibeere lori idanilẹkọ naa.
Go to the Top