Display Videos ( 101 - 125 of: 285 )
Orukọ Ọlọhun ( Al-Haliim )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Haliim ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rọuuf )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rọuuf ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Al-Gaffaar )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Gaffaar ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Al-Gafuur )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Gafuur ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Al-A’fuwwu )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-A’fuwwu ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rọhiim )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rọhiim ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rahmaan )(Yoruba)
2016-04-22
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rahmaan ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Itumọ Aye labẹ Agbọye Islam - 2(Yoruba)
2016-03-30
Sise afihan bi eniyan se nifẹ si aye pupọ ati ọrọ nipa awọn nkan ti o jẹ iranlọwọ lati ma si aye lo
2016-03-30
Idahun si iruju awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si (Al-Kur’aniyuun).
2016-03-30
Alaye lori ibasepọ Sunnah ati Alukuraani, anfaani Sunnah nibi igbagbọye Alukuraani ati idahun si iruju awọn ijọ yii.
2016-03-30
Alaye awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si. Kinni adisọkan wọn? Bawo ni awọn ijọ yii se sẹ yọ, ta si ni olori wọn
2016-03-30
Alaye imọra ati ọna ti o pin si pẹlu alaye ohun ti a le fi gbe ẹgbin kuro lara gẹgẹ bii omi ati awọn idajọ shariah ti o rọ mọ ọ
2016-03-30
Itẹsiwaju alaye lori ipin Imọra pẹlu awọn idajọ wọn labẹ ofin Shariah Islam
2016-03-30
Abala yii jẹ abala idahun si ibeere ọlọkan-ọ-jọkan.
Jijẹ Onisowo Musulumi Rere -2(Yoruba)
2016-02-18
Itẹsiwaju ninu alaye nipa idajọ Sharia lori owo sise, awọn ẹkọ ti o yẹ ki onisowo se amulo rẹ. Lẹyin eyi akiyesi waye lori awọn irori kan ti o pepe si atunse nipa owo sise.
Jijẹ Onisowo Musulumi Rere -1(Yoruba)
2016-02-18
Alaye lori itumọ owo sise pẹlu apejuwe rẹ ninu igbesi aye awọn Sahabe Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], lẹyin eyi ni ọrọ waye nipa idajọ Sharia lori owo sise.
2016-02-17
Afikun idahun si ibeere.
2016-02-17
Adadaalẹ ti o ma nwaye nibi isẹ hajj sise, ti idahun si ibeere si jẹ ohun ti o tẹlee.
2016-02-17
Alaye lori awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu awọn osu oju ọrun: Osu Rọbiul-Awwal titi de Dhul Hijjah.
2016-02-17
Awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu osu Muharram ati Osu Sọfar.
2016-02-17
Awọn ọla ti n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti ibeere ati idahun si tẹle e.
2016-02-17
Diẹ ninu awọn iwa ti o rẹwa ti o n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti wọn si tun sọ diẹ lara awọn ọla ti o n bẹ fun un.
2016-02-17
Khadijah jẹ ẹniti awọn ara ilu Mẹkkah gba pe o mọ ninu awọn obinrin ki ẹsin Islam too de, oun si ni ẹni akọkọ ti o kọkọ gba Islam.