Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam
Subject Information
Title: Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.
2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.
2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.
Addition Date: 2014-12-10
Short Link: http://IslamHouse.com/794595
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa - Ede Amariki - Awọn ara Sinhale - Awọn ara Rọọsia - Afar - Tigrinya - Malayalam