Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina
Subject Information
Title: Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina
Language: Yoruba
The Writer: Rafiu Adisa Bello
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.
Addition Date: 2014-12-09
Short Link: http://IslamHouse.com/794555
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa