Ojise Aanu

Audios Subject Information
Title: Ojise Aanu
Language: Yoruba
Short Discription: 1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata.
2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi san ibi.
3- Apejuwe lori aanu ti ojise Olohun ni fun awon eranko. Ikilo si waye lori fifi iya je awon eranko.
4- Apejuwe nipa aanu re si awon ewe tabi awon omode.
5- Apejuwe nipa aanu ojise Olohun si awon obinrin, oro si waye lori bi awon eniyan se maa nse abosi si won ni igba aimokan.
6- Awon apejuwe nipa iteriba ati iwapele ojise Olohun. Bi o ti se ni aanu awon omoleyin re ti awon naa si ni ife si i.
Addition Date: 2014-02-20
Short Link: http://IslamHouse.com/461646
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 6 )
1.
Ojise Aanu - 1
9.2 MB
Listen: Ojise Aanu - 1.mp3
2.
Ojise Aanu - 2
9.2 MB
Listen: Ojise Aanu - 2.mp3
3.
Ojise Aanu - 3
9.7 MB
Listen: Ojise Aanu - 3.mp3
4.
Ojise Aanu - 4
9.5 MB
Listen: Ojise Aanu - 4.mp3
5.
Ojise Aanu - 5
9.6 MB
Listen: Ojise Aanu - 5.mp3
6.
Ojise Aanu - 6
6.1 MB
Listen: Ojise Aanu - 6.mp3
Go to the Top