Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah
Subject Information
Title: Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Koko ibanisọrọ yii ni: (i) Itumọ atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun (ii) Awọn ọna ti a ngba se atẹgun lati wa oore ni ọdọ Ọlọhun. (iii) Awọn gbolohun ti o lẹtọ ti Musulumi fi le se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun.
Addition Date: 2015-02-11
Short Link: http://IslamHouse.com/812018
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa