Iwọ Aladugbo

Audios Subject Information
Title: Iwọ Aladugbo
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ.
2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
Addition Date: 2014-12-10
Short Link: http://IslamHouse.com/794620
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 2 )
1.
Iwọ Aladugbo -1
26 MB
Listen: Iwọ Aladugbo -1.mp3
2.
Iwọ Aladugbo -2
26.2 MB
Listen: Iwọ Aladugbo -2.mp3
Go to the Top