Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ
Subject Information
Title: Itumọ Wiwa Alubarika ati Awọn Ipin rẹ
Language: Yoruba
The Writer: Rafiu Adisa Bello
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Akosile yi so oro lori ohun ti a npe ni wiwa alubarika bi awon onimimo se se alaye re, leyinnaa o so nipa awon ipin wiwa alubarika eyi ti o pin si meji: eyi ti o leto ati eyi ti ko leto ti oro si tun waye lori awon nkan ti Olohun fi alubarika si ara won ti o si se e leto lati fi won wa alubarika.
Addition Date: 2014-12-07
Short Link: http://IslamHouse.com/794258
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa