Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam

Audios Subject Information
Title: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh.
3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o.
4- Oro waye ni apa kerin yi lori Pataki yiyara lo si mosalasi ni ojo Jimoh ati Pataki titeti si Imam ni asiko khutuba, bakannaa ojuse eni ti o ba tete de mosalasi ati eni ti o pe de mosalasi nibi nafila ti a n pe ni "Tahiyyatul-masjid".
5- Oro waye ninu apa karun yi lori awon suura ti Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- maa n ka ninu irun Jimoh ati irun odun mejeeji pelu alaye awon eko ti o wa ninu awon suura naa, oludanileko si tun menu ba awon idajo ti o n be fun awon irun odun mejeeji ti odun ba bo si ojo Jimoh.
6- Alaye wa ninu apa kefa yi lori: (1) Nafila eyin irun Jimoh ati iye onka rakaa re. (2) Iwe fun irun Jimoh, se oranyan ni tabi kiise oranyan. (3) Awon ibeere lori oro Jimoh ati gbogbo ohun ti o ropo mo o pelu idahun lori won.
Addition Date: 2014-04-23
Short Link: http://IslamHouse.com/535826
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 5 )
1.
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -2
16.6 MB
Listen: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -2.mp3
2.
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -3
18.8 MB
Listen: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -3.mp3
3.
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -4
74.1 MB
Listen: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -4.mp3
4.
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -5
18.4 MB
Listen: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -5.mp3
5.
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -6
18.7 MB
Listen: Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam -6.mp3
Go to the Top