Die Ninu Awon Ewa Islam

Audios Subject Information
Title: Die Ninu Awon Ewa Islam
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdul-jeleel Alagufon
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.
2- Ninu awon Ewa esin Islam ti oniwaasi menu ba ninu apa keji yi ni bi Islam se je esin gbogbo abgaye, ti o tun je esin ti o pe perepere, bakannaa ti o si je esin ti o rorun julo.
Addition Date: 2014-04-22
Short Link: http://IslamHouse.com/535767
Attachments ( 2 )
1.
Die Ninu Awon Ewa Islam - 1
48.3 MB
Listen: Die Ninu Awon Ewa Islam - 1.mp3
2.
Die Ninu Awon Ewa Islam - 2
31.7 MB
Listen: Die Ninu Awon Ewa Islam - 2.mp3
Go to the Top