Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si

Audios Subject Information
Title: Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si
Language: Yoruba
Short Discription: Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin isokan fun awa Musulumi. Sugbon apa kan ninu awon janmoo yi ni awon aleebu kookan gege bii ki a gba wipe olori janmoo ko le se asise ati wipe janmoo ti a ba wa ninu re nikan ni ona sunna ti o dara julo, irufe awon nkan yii ni olubanisoro menu ba ninu waasi yi.
Addition Date: 2013-12-02
Short Link: http://IslamHouse.com/450251
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 1 )
1.
Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si
98.7 MB
Listen: Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si.mp3
Go to the Top