Ile Musulumi - 2

Videos Subject Information
Title: Ile Musulumi - 2
Language: Yoruba
Short Discription: Olubanisoro so ninu apa keji waasi yi Pataki ki oko maa na owo le iyawo re lori, o si je ki a mo wipe ojuse ti Olohun se ni dandan fun un ni, Olohun si ti se adehun lati maa fi opolopo ropo ti o ba ti n na fun iyawo re. Bakanna ni oniwaasi so awon aleebu ti o wa lodo enikookan ninu oko ati iyawo ti o si gba won ni imoran lati fi won sile.
Addition Date: 2013-11-25
Short Link: http://IslamHouse.com/449123
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Ile Musulumi - 2
284.8 MB
2.
449123.mp3
60 MB
Listen: 449123.mp3.mp3
Also... ( 1 )
Go to the Top