Igbagbo Ododo
Subject Information
Title: Igbagbo Ododo
Language: Yoruba
The Lecturer: Isa Akindele Solahudeen
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Ibanisoro yi da lori igbagbo ninu Olohun ati alaye itumo re. Olubanisoro yi se alaye pupo lori itumo ohun ti o nje igbagbo, o si fi awon apeere laakaye ba awon eniyan soro pupo nibe nitoripe eleyi ni o ba awon ogooro eniyan ti won wa ni ijoko naa mu. Bakannaa ni o fi awon eri Al-kurani ati hadiisi se alaye.
Addition Date: 2013-11-25
Short Link: http://IslamHouse.com/449111
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...