Awon Ohun ti o je Ojuse Eni ti o sese gba Esin Islam

Videos Subject Information
Title: Awon Ohun ti o je Ojuse Eni ti o sese gba Esin Islam
Language: Yoruba
Short Discription: Oniwaasi so Pataki esin Islam o si je ki awon eniyan mo wipe gbigba esin Islam kiise mimoose enikan bikose aanu Olohun lori eni naa. Bakannaa o tun so iyato ti o wa laarin Islam ati awon esin yoku, ti o si so awon majemu ti o maa nje ki ise Musulumi di atewogba ni iwaju Olohun. Ni ipari o ba awon ti won gba Islam dupe, o fun won ni iro wipe Olohun maa nfi esin Islam pa awon ese ti eniyan ba ti se koja re, lehinnaa o so fun won bi o ti se je Pataki ki won jinna si ebo sise.
Addition Date: 2013-11-25
Short Link: http://IslamHouse.com/449103
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Awon Ohun ti o je Ojuse Eni ti o sese gba Esin Islam
286.1 MB
2.
449103.mp3
87.4 MB
Listen: 449103.mp3.mp3
Go to the Top