Oro Nipa Awon Alujannu - 2

Videos Subject Information
Title: Oro Nipa Awon Alujannu - 2
Language: Yoruba
Short Discription: Olubanisoro tun se alaye nipa bi awon alujannu se maa nlo awon eniyan ti won ba gbe ara won si ipo eniti won yoo maa ke pe ti won yoo si maa gbe aworan won wo lati fi so awon eniyan nu. Ni ipari, olubanisoro yi so nipa awon ona ti Musulumi yoo fi maa wa iso pelu Olohun ti alujannu ati awon eni esu ti won maa nlo won ko fi le ni agbara lori wa.
Addition Date: 2013-11-18
Short Link: http://IslamHouse.com/448662
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Oro Nipa Awon Alujannu - 2
230.2 MB
2.
448662.mp3
60 MB
Listen: 448662.mp3.mp3
Also... ( 1 )
Go to the Top