Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe

Videos Subject Information
Title: Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe
Language: Yoruba
Short Discription: Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe ki won si awon ilekun ogba idera Al-janna sile ti Yoo si pa ase pe ki won ti gbogbo awon ilekun ina ti won yoo si de gbogbo awon esu mole. Olubanisoro tun so ni ekunrere oro nipa ilana ojise Olohun lori bibere aawe.
Addition Date: 2013-11-18
Short Link: http://IslamHouse.com/448658
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe
294.7 MB
2.
448658.mp3
89.9 MB
Listen: 448658.mp3.mp3
Go to the Top