Pataki Oro Omode ninu Islam
Subject Information
Title: Pataki Oro Omode ninu Islam
Language: Yoruba
The Lecturer: Dhikrullah Shafihi
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Khutba yi da lori oro nipa awon omode ati bi won ti se Pataki ni awujo. Oniwaasi fi oro yi se khutuba ni ibamu pelu ojo ti orile-ede Nigeria mu gege bii ojo awon ewe (omode). O si se alaye pupo nipa bi esin Islam ti se amojuto awon omode.
Addition Date: 2013-11-18
Short Link: http://IslamHouse.com/448626
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...