Eko nipa Odun Itunu Aawe
Subject Information
Title: Eko nipa Odun Itunu Aawe
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur Rosheed Abdul Jabaar (Buwaeb)
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi laruge. Ojise Olohun si pase wipe ki gbogbo Musulumi jade lo si aaye ikirun fun odun yii.
Addition Date: 2013-11-10
Short Link: http://IslamHouse.com/448380
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...