NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA?
Subject Information
Title: NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA?
Language: Yoruba
The Writer: Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti won yoo si lero wipe anabi ni ti o si je wipe Esu ko ni agbara lati gbe aworan anabi wa Muhammad wo.
Addition Date: 2013-06-11
Short Link: http://IslamHouse.com/429411
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa