Itọju Awọn Obi

Videos Subject Information
Title: Itọju Awọn Obi
Language: Yoruba
The Lecturer: Qomorudeen Yunus
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: [1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni.
[2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji.
[3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ.
[4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ lati ọdọ awọn sahabe Anọbi.
[5] Awọn anfaani ti o wa nibi daada sise si awọn obi ẹni.
Alaye nipa sise daada si awọn obi ẹni lẹyin ti wọn ti jade laye.
Addition Date: 2015-12-04
Short Link: http://IslamHouse.com/2783389
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 3 )
1.
Itọju Awọn Obi
275.6 MB
2.
Itọju Awọn Obi
3.
2783389.mp3
31.5 MB
Listen: 2783389.mp3.mp3
Also... ( 1 )
Go to the Top