Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo

Audios Subject Information
Title: Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii:
(i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo,
(ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii,
(iii) Majẹmu Rukiya,
(iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun,
(v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.
Addition Date: 2015-04-10
Short Link: http://IslamHouse.com/829543
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 1 )
1.
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
27.1 MB
Listen: Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo.mp3
Go to the Top