Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu
Subject Information
Title: Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ.
2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
Addition Date: 2015-01-12
Short Link: http://IslamHouse.com/805550
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Also... ( 2 )