Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ

Title: Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
Addition Date: 2015-01-04
Short Link: http://IslamHouse.com/803815
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa