Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam

Audios Subject Information
Title: Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.
2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.
Addition Date: 2014-12-10
Short Link: http://IslamHouse.com/794595
Attachments ( 2 )
1.
Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam -1
25.5 MB
Listen: Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam -1.mp3
2.
Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam -2
26.3 MB
Listen: Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam -2.mp3
Go to the Top