Awon Arun Okan

Title: Awon Arun Okan
Language: Yoruba
The Lecturer: Isa Akindele Solahudeen
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: 1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan.
2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.
2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.
Addition Date: 2014-03-25
Short Link: http://IslamHouse.com/474229
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa