Taani Olohun- 2

Videos Subject Information
Title: Taani Olohun- 2
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Olubanisọrọ tẹsiwaju ninu alaye awọn nkan ti o maa nse akoba fun Taoheed ninu iran Ẹbọ sise ati okunfa re, gẹgẹ bii Mima se ijọsin nibi saare oku, Gbigbẹ saare si inu mọsalaasi, Tita ẹjẹ silẹ fun nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, Wiwa idaabobo tabi iranlọwọ lọdọ nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah. Ni akotan, wọn jẹ ki a mọ pe iru awọn nkan bayi le se akoba wiwọ Alujannah Musulumi.
Addition Date: 2014-02-06
Short Link: http://IslamHouse.com/461037
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 3 )
1.
Taani Olohun- 2
277.7 MB
2.
Taani Olohun- 2
3.
461037.mp3
31.7 MB
Listen: 461037.mp3.mp3
Also... ( 1 )
Go to the Top