Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo

Videos Subject Information
Title: Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo
Language: Yoruba
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo nkan di Bidi’ah, 6- fifun ilẹ mọni nibiti igbalaye wa ki gbolohun pe meji nibẹ. Ni igbẹyin, olubanisọrọ jẹ ki a mọ wipe gbigba Sunnah mu nikan ni o le yọ wa nibi aseju tabi aseeto.
Addition Date: 2014-02-06
Short Link: http://IslamHouse.com/461033
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 3 )
1.
Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo
520.5 MB
2.
Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo
3.
461033.mp3
58.9 MB
Listen: 461033.mp3.mp3
Go to the Top