Alaye Lori Sunna Ati Pataki Re Nibi Agboye Esin
Subject Information
Title: Alaye Lori Sunna Ati Pataki Re Nibi Agboye Esin
Language: Yoruba
The Lecturer: Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Reviewing: Hamid Yusuf
Short Discription: Olubanisoro se ni alaye lekunrere nkan ti won npe ni Sunna, o so pelu akori wipe odidi esin Islam ni Sunna atipe Sunna gan an ni esin Islam. O tesiwaju ninu alaye re wipe agboye Alkurani ko rorun fun Musulumi bikose latari Sunna, bee si ni Sunna je aayan ongbifo fun Alkurani Alaponle.
Addition Date: 2014-01-13
Short Link: http://IslamHouse.com/453367
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa