Kinni o nje Sunna ?
Subject Information
Title: Kinni o nje Sunna ?
Language: Yoruba
The Lecturer: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Ibanisoro yi so nipa itumo sunna, o si je ki a mo igba ti awon Musulumi bere si pe awon kan ni oni sunna. Ni ipari alaye tun waye lori awon apeere ti a fi maa nda awon oni sunna mo; nitoripe opolopo naa ni won maa npe ara won ni oni sunna ti won si jinna si i.
Addition Date: 2013-12-02
Short Link: http://IslamHouse.com/450256
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa