Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna

Audios Subject Information
Title: Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna
Language: Yoruba
Short Discription: Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
Addition Date: 2013-12-02
Short Link: http://IslamHouse.com/450247
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 1 )
1.
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna
156.3 MB
Listen: Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna.mp3
Go to the Top