Ijosin Ninu Islam

Title: Ijosin Ninu Islam
Language: Yoruba
The Lecturer: Qomorudeen Yunus
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Ibanisoro yi da lori ijosin ati itumo re, oniwaasi so Pataki ki Musulumi se akiyesi awon majemu ijosin mejeeji: awon naa ni sise afomo ise fun Olohun ati sise ise ijosin naa ni ibamu pelu bi ojise Olohun ti se e. Lehinnaa ni o menu baa won oniran iran ijosin gege bii irun kiki aawe saka haj ati beebeelo. Ni ipari o so nipa awon nkan ti o maa nba ijosin je, eyi ti o sit obi ju ninu re naa ni ebo sise pelu Olohun.
Addition Date: 2013-11-25
Short Link: http://IslamHouse.com/449138
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...