Itoju Awon Arun ni Ilana Islam
Subject Information
Title: Itoju Awon Arun ni Ilana Islam
Language: Yoruba
The Lecturer: Isa Akindele Solahudeen
Reviewing: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Waasi yi so nipa awon ona iwosan ninu Islam. Oniwaasi so wipe awon aisan ti o maa nse awon eniyan pin si meji: aisan emin ati aisan ara. O si so wipe iso ti o dara julo nibi gbogbo arun naa ni iberu Olohun ati gbigbe ara le E. Lehinnaa, olubanisoro je ki a mo wipe kosi aisan ti ko ni itoju ayafi aisan ogbo. Bakannaa ni o menu ba die ninu awon nkan ti a fi maa nse itoju arun gege bii oyin, omi samsam ati beebeelo.
Addition Date: 2013-11-25
Short Link: http://IslamHouse.com/449125
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...