Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 1

Videos Subject Information
Title: Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 1
Language: Yoruba
The Lecturer: Dhikrullah Shafihi
Short Discription: Khutba yi so nipa bi Musulumi yoo se mura sile fun osu Ramadan lati gba aawe nibe ati lati se awon naafila nibe. O so nipa bi awon eni isiwaju ninu esin se maa n pade osu Ramadan pelu idunnu ati ayo, ti won si maa n banuje ti o ba tan. Olubanisoro tun menu ba bi osu Shaaban se je osu imurasile ati yiye ara eni wo fun osu aawe Ramadan. O tun so nipa awon adadasile ti awon eniyan maa nse, o si so pe ki awon Musulumi jinna sii nitoripe esin ti di pipe ki ojise Olohun to fi aye sile.
Addition Date: 2013-11-18
Short Link: http://IslamHouse.com/448629
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 1
125 MB
2.
448629.mp3
30.5 MB
Listen: 448629.mp3.mp3
Also... ( 1 )
Go to the Top