Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won

Videos Subject Information
Title: Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won
Language: Yoruba
Short Discription: Sise daadaa si awon obi je ojuse Pataki ti Olohun pa omo ni ase re leyin ti o pase wipe ko gbodo josin fun nkan miran yato si Oun Olohun. Eleyi ni ohun ti ibanisoro yi da lelori, olubanisoro si mu awon apejuwe lori oore ti o wa ninu ki eniyan maa se daadaa si awon obi ati aburu ti o wa nibi ki eniyan maa se aidaa si won.
Addition Date: 2013-11-12
Short Link: http://IslamHouse.com/448463
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Loading the player...
Attachments ( 2 )
1.
Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won
39.1 MB
2.
448463.mp3
12.4 MB
Listen: 448463.mp3.mp3
Go to the Top