Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna

Audios Subject Information
Title: Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna
Language: Yoruba
The Lecturer: Rafiu Adisa Bello
Short Discription: Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.
Addition Date: 2013-11-11
Short Link: http://IslamHouse.com/448398
Translation of Subject Description: Awọn ara ilẹ Larubawa
Attachments ( 1 )
1.
Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna
99 MB
Listen: Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna.mp3
Go to the Top